Num 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o ma pa aṣẹ rẹ̀ mọ́, ati aṣẹ gbogbo ajọ niwaju agọ́ ajọ, lati ṣe iṣẹ-ìsin agọ́.

Num 3

Num 3:1-10