Num 26:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi ni idile awọn ọmọ Aṣeri gẹgẹ bi awọn ti a kà ninu wọn; nwọn jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje.

Num 26

Num 26:40-51