Num 26:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi ni idile awọn ọmọ Gadi gẹgẹ bi awọn ti a kà ninu wọn, nwọn jẹ́ ọkẹ meji o le ẹdẹgbẹta.

Num 26

Num 26:14-28