Num 25:17-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. Yọ awọn ara Midiani lẹnu, ki o si kọlù wọn.

18. Nitoriti nwọn fi ẹ̀tan wọn yọ nyin lẹnu, eyiti nwọn tàn nyin niti ọ̀ran Peori, ati niti ọ̀ran Kosbi, ọmọ ijoye Midiani kan, arabinrin wọn, ẹniti a pa li ọjọ́ àrun nì niti ọ̀ran Peori.

Num 25