Num 23:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si fi ọ̀rọ si Balaamu li ẹnu, o si wipe, Pada tọ̀ Balaki lọ, bayi ni ki iwọ ki o si sọ.

Num 23

Num 23:1-8