Num 23:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Balaki si ṣe bi Balaamu ti wi; ati Balaki ati Balaamu fi akọmalu kan ati àgbo kan rubọ lori pẹpẹ kọkan.

Num 23

Num 23:1-10