Num 21:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si yipada, nwọn si gòke lọ li ọ̀na Baṣani: Ogu ọba Baṣani si jade tọ̀ wọn lọ, on, ati gbogbo awọn enia rẹ̀, si ogun ni Edrei.

Num 21

Num 21:32-35