Num 21:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Israeli si gbà gbogbo ilunla wọnni: Israeli si joko ninu gbogbo ilunla ti awọn ọmọ Amori, ni Heṣboni, ati ni ilu rẹ̀ gbogbo.

Num 21

Num 21:21-29