Num 21:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Israeli si jẹ́ ẹjẹ́ fun OLUWA, wipe, Bi iwọ ba fi awọn enia yi lé mi lọwọ nitõtọ, njẹ emi o run ilu wọn patapata.

Num 21

Num 21:1-6