Num 21:19-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ati Mattana nwọn lọ si Nahalieli: ati lati Nahalieli nwọn lọ si Bamotu:

20. Ati lati Bamotu li afonifoji nì, ti mbẹ ni ilẹ Moabu, si óke Pisga, ti o si kọjusi aginjù.

21. Israeli si rán onṣẹ si Sihoni ọba awọn ọmọ Amori, wipe,

Num 21