Num 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati ibẹ̀ nwọn si lọ si Beeri: eyinì ni kanga eyiti OLUWA sọ fun Mose pe, Pe awọn enia jọ, emi o si fun wọn li omi.

Num 21

Num 21:11-25