Num 18:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si jẹ ẹ ni ibi gbogbo, ati ẹnyin ati awọn ara ile nyin: nitoripe ère nyin ni fun iṣẹ-ìsin nyin ninu agọ́ ajọ.

Num 18

Num 18:23-32