Num 16:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ni ijọ́ keji gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli nkùn si Mose ati si Aaroni, wipe, Ẹnyin pa awọn enia OLUWA.

Num 16

Num 16:38-45