Num 15:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iwọ ba si pèse ẹgbọrọ akọmalu kan fun ẹbọ sisun, tabi fun ẹbọ kan, lati san ẹjẹ́, tabi ẹbọ alafia si OLUWA:

Num 15

Num 15:7-13