Num 15:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o si múwa fun ẹbọ ohunmimu àbọ òṣuwọn hini ọti-waini, ẹbọ ti a fi iná ṣe, õrùn didùn si OLUWA.

Num 15

Num 15:1-15