Num 14:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Joṣua ọmọ Nuni, ati Kalebu ọmọ Jefunne, ninu awọn ọkunrin na ti o rìn ilẹ na lọ, wà lãye.

Num 14

Num 14:37-45