Num 14:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo ijọ si wipe ki a sọ wọn li okuta. Ṣugbọn ogo OLUWA hàn ninu agọ́ ajọ niwaju gbogbo awọn ọmọ Israeli.

Num 14

Num 14:5-17