Num 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li orukọ awọn ọkunrin na, ti Mose rán lati lọ ṣe amí ilẹ na. Mose si sọ Oṣea ọmọ Nuni ni Joṣua.

Num 13

Num 13:13-17