Num 13:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) OLUWA si sọ fun Mose pe, Rán enia, ki nwọn ki o si ṣe amí ilẹ Kenaani, ti mo fi fun awọn ọmọ Israeli