Num 11:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wi fun u pe, Iwọ njowú nitori mi? gbogbo enia OLUWA iba le jẹ́ wolĩ, ki OLUWA ki o fi ẹmi rẹ̀ si wọn lara!

Num 11

Num 11:25-32