Num 10:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ogun ọjọ́ oṣù keji, li ọdún keji, ni awọsanma ká soke kuro lori agọ́ ẹrí.

Num 10

Num 10:4-15