Num 10:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA si sọ fun Mose pe,

2. Iwọ ṣe ipè fadakà meji; iṣẹ́-ọnà lilù ni ki o ṣe wọn: iwọ o si ma fi wọn pè ajọ, iwọ o si ma fi wọn ṣí ibudó.

Num 10