Num 1:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki awọn ọmọ Israeli ki o si pa agọ́ wọn, olukuluku ni ibudó rẹ̀, ati olukuluku lẹba ọpagun rẹ̀, gẹgẹ bi ogun wọn.

Num 1

Num 1:48-54