Num 1:46-48 Yorùbá Bibeli (YCE)

46. Ani gbogbo awọn ti a kà o jẹ́ ọgbọ̀n ọkẹ enia o le egbejidilogun din ãdọta.

47. Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi ẹ̀ya baba wọn li a kò kà mọ́ wọn.

48. Nitoripe OLUWA ti sọ fun Mose pe,

Num 1