Num 1:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li awọn ti a kà, ti Mose ati Aaroni kà, ati awọn olori Israeli, ọkunrin mejila: olukuluku wà fun ile awọn baba rẹ̀.

Num 1

Num 1:39-47