Num 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ọkunrin kọkan lati inu olukuluku ẹ̀ya ki o si wà pẹlu nyin; ki olukuluku jẹ́ olori ile awọn baba rẹ̀.

Num 1

Num 1:2-6