Neh 7:13-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Awọn ọmọ Sattu, ojilelẹgbẹrin o le marun.

14. Awọn ọmọ Sakkai, ojidilẹgbẹrin.

15. Awọn ọmọ Binnui, ojilelẹgbẹta o le mẹjọ.

16. Awọn ọmọ Bebai, ẹgbẹta o le mejidilọgbọn.

17. Awọn ọmọ Asgadi, egbejila o di mejidilọgọrin.

18. Awọn ọmọ Adonikamu ọtalelẹgbẹta o le meje.

Neh 7