3. Ṣekaniah, Rehumu, Meremoti,
4. Iddo, Ginneto, Abijah,
5. Miamini, Maadiah, Bilga,
6. Ṣemaiah, ati Joiaribu, Jodaiah,
7. Sallu, Amoku, Hilkiah, Jedaiah. Wọnyi li olori awọn alufa, ati ti awọn arakunrin wọn li ọjọ Jeṣua.
8. Ati awọn ọmọ Lefi: Jeṣua, Binnui, Kadmieli, Ṣerebiah, Juda, ati Mattaniah, ti o wà lori orin idupẹ, on ati awọn arakunrin rẹ̀.
9. Bakbukiah pẹlu ati Unni, awọn arakunrin wọn, li o kọju si wọn ninu iṣọ.
10. Jeṣua si bi Joiakimu, Joiakimu si bi Eliaṣibu, Eliaṣibu si bi Joiada,
11. Joiada si bi Jonatani, Jonatani si bi Jaddua.