Neh 12:13-17 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Ti Esra, Meṣullamu; ti Amariah, Jehohanani;

14. Ti Meliku, Jonatani; ti Ṣebaniah, Josefu;

15. Ti Harimu, Adna; ti Meraioti, Helkai;

16. Ti Iddo, Sekariah; ti Ginnetoni, Meṣullamu;

17. Ti Abijah, Sikri; ti Miniamini, ti Moadiah, Piltai:

Neh 12