Neh 11:35-36 Yorùbá Bibeli (YCE) Lodi, ati Ono, afonifoji awọn oniṣọnà, Ati ninu awọn ọmọ Lefi, awọn ìpín Juda si ngbe ilẹ Benjamini.