Neh 11:34-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

34. Hadidi, Seboimu, Neballati,

35. Lodi, ati Ono, afonifoji awọn oniṣọnà,

36. Ati ninu awọn ọmọ Lefi, awọn ìpín Juda si ngbe ilẹ Benjamini.

Neh 11