Neh 11:33-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

33. Hasori, Rama, Gittaimu,

34. Hadidi, Seboimu, Neballati,

35. Lodi, ati Ono, afonifoji awọn oniṣọnà,

36. Ati ninu awọn ọmọ Lefi, awọn ìpín Juda si ngbe ilẹ Benjamini.

Neh 11