Neh 11:28-36 Yorùbá Bibeli (YCE)

28. Ati ni Siklagi, ati ni Mekona, ati ninu ileto rẹ̀,

29. Ati ni En-rimmoni, ati ni Sarea, ati Jarmuti,

30. Sanoa, Adullamu, ati ileto wọn, ni Lakiṣi, ati oko rẹ̀, ni Aseka, ati ileto rẹ̀. Nwọn si ngbe lati Beerṣeba titi de afonifoji Hinnomu.

31. Ati awọn ọmọ Benjamini lati Geba de Mikmaṣi, ati Aija, ati Beteli, ati ileto wọn.

32. Ni Anatotu, Nobu, Ananiah,

33. Hasori, Rama, Gittaimu,

34. Hadidi, Seboimu, Neballati,

35. Lodi, ati Ono, afonifoji awọn oniṣọnà,

36. Ati ninu awọn ọmọ Lefi, awọn ìpín Juda si ngbe ilẹ Benjamini.

Neh 11