9. Ati awọn ọmọ Lefi: ati Jeṣua ọmọ Asaniah, Binnui, ọkan ninu awọn ọmọ Henadadi, Kadmieli;
10. Ati awọn arakunrin wọn, Ṣebaniah, Hodijah, Kelita, Pelaiah, Hanani,
11. Mika, Rehobu, Haṣabiah,
12. Sakkuri, Ṣerebiah, Ṣebaniah,
13. Hodijah, Bani, Beninu.
14. Awọn olori awọn enia; Paroṣi, Pahati-moabu, Elamu, Sattu, Bani.
15. Bunni, Asgadi, Bebai,