Neh 10:19-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Harifi, Anatoti, Nebai,

20. Magpiaṣi, Meṣullamu, Hasiri,

21. Meṣesabeeli, Sadoku, Jaddua,

22. Pelatiah, Hanani, Anaiah,

23. Hoṣea, Hananiah, Haṣubu,

24. Halloheṣi, Pileha, Ṣobeki,

25. Rehumu, Hasabna, Maaseiah,

26. Ati Ahijah, Hanani, Anani,

27. Malluku, Harimu, Baana.

28. Ati awọn enia iyokù, awọn alufa, awọn ọmọ Lefi, awọn adèna, awọn akọrin, awọn Netinimu, ati gbogbo awọn ti o ya ara wọn kuro lọdọ awọn enia ilẹ na si ofin Ọlọrun, aya wọn, awọn ọmọ wọn ọkunrin, ati awọn ọmọ wọn obinrin, gbogbo ẹniti o ni ìmọ ati oye;

Neh 10