Neh 10:1-8 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AWỌN ti o fi èdidi di i ni Nehemiah, bãlẹ, ọmọ Hakaliah, ati Sidkijah.

2. Seraiah, Asariah, Jeremiah,

3. Paṣuri, Amariah, Malkijah,

4. Hattuṣi, Ṣebaniah, Malluki,

5. Harimu, Meremoti, Obadiah,

6. Danieli, Ginnetoni, Baruki,

7. Meṣullamu, Abijah, Mijamini,

8. Maaṣiah, Bilgai, Ṣemaiah: alufa li awọn wọnyi.

Neh 10