Neh 10:1-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AWỌN ti o fi èdidi di i ni Nehemiah, bãlẹ, ọmọ Hakaliah, ati Sidkijah.

2. Seraiah, Asariah, Jeremiah,

3. Paṣuri, Amariah, Malkijah,

4. Hattuṣi, Ṣebaniah, Malluki,

5. Harimu, Meremoti, Obadiah,

6. Danieli, Ginnetoni, Baruki,

Neh 10