Nah 2:12-13 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Kiniun ti fàya pẹrẹpẹrẹ tẹrùn fun awọn ọmọ rẹ̀, o si fun li ọrun pa fun awọn abo kiniun rẹ̀, o si fi ohun ọdẹ kún isà rẹ̀, ati ihò rẹ̀ fun onjẹ agbara.

13. Kiyesi i, emi dojukọ ọ, ni Oluwa awọn ọmọ ogun wi, emi o si fi kẹkẹ́ rẹ̀ wọnni joná ninu ẹ̃fin, idà yio si jẹ ọmọ kiniun rẹ wọnni run: emi o si ke ohun ọdẹ rẹ kuro lori ilẹ aiye, ohùn awọn ojiṣẹ rẹ li a kì yio si tún gbọ́ mọ.

Nah 2