Mik 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn oke nla yio si yọ́ labẹ rẹ̀, awọn afonifojì yio si pinyà, bi ida niwaju iná, bi omi ti igbálọ ni ibi gẹ̀rẹgẹ̀rẹ.

Mik 1

Mik 1:1-11