Mik 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kọja lọ, iwọ ará Safiri, pẹlu itiju rẹ ni ihòhò: ara Saanani kò jade wá; ọ̀fọ̀ Beteseli yio gba iduro rẹ̀ lọwọ nyin.

Mik 1

Mik 1:10-16