Mat 9:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati o ri ọ̀pọ enia, ãnu wọn ṣe e, nitoriti ãrẹ̀ mu wọn, nwọn, si tuká kiri bi awọn agutan ti ko li oluṣọ.

Mat 9

Mat 9:31-38