Mat 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si nà ọwọ́ rẹ̀, o fi bà a, o wipe, Mo fẹ; iwọ di mimọ́. Lojukanna ẹ̀tẹ rẹ̀ si mọ́.

Mat 8

Mat 8:2-11