Mat 7:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ mã kiyesi awọn eke woli ti o ntọ̀ nyin wá li awọ agutan, ṣugbọn apanijẹ ikõkò ni nwọn ninu.

Mat 7

Mat 7:9-22