Mat 6:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹ tò iṣura jọ fun ara nyin li ọrun, nibiti kòkoro ati ipãra ko le bà a jẹ, ati nibiti awọn olè kò le runlẹ ki nwọn si jale.

Mat 6

Mat 6:15-30