Mat 6:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bi ẹnyin ba fi ẹ̀ṣẹ awọn enia jì wọn, Baba nyin ti mbẹ li ọrun yio fi ẹ̀ṣẹ ti nyin jì nyin.

Mat 6

Mat 6:13-21