Mat 6:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kiyesi ara ki ẹ máṣe itọrẹ anu nyin niwaju enia, ki a ba le ri nyin: bi o ba ri bẹ̃, ẹnyin ko li ère lọdọ Baba nyin ti mbẹ li ọrun.

Mat 6

Mat 6:1-6