Mat 5:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi wi fun nyin, Ẹ máṣe kọ̀ ibi; ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba gbá ọ li ẹrẹkẹ ọtún, yi ti òsi si i pẹlu.

Mat 5

Mat 5:36-44