Mat 5:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni a kì itàn fitila tan, ki a si fi i sabẹ òṣuwọn; bikoṣe lori ọpá fitila, a si fi imọlẹ fun gbogbo ẹniti mbẹ ninu ile.

Mat 5

Mat 5:12-22