Mat 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Alabukún-fun li ẹnyin, nigbati nwọn ba nkẹgan nyin, ti nwọn ba nṣe inunibini si nyin, ti nwọn ba nfi eke sọ̀rọ buburu gbogbo si nyin nitori emi.

Mat 5

Mat 5:5-14