Mat 27:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o da Barabba silẹ fun wọn. Ṣugbọn o nà Jesu, o si fi i le wọn lọwọ lati kàn a mọ agbelebu.

Mat 27

Mat 27:18-35